Omolara Aya Lawal Olumegbon O. O.
(Ekùn ìdibò Erékùsù Èkó Kinní): Olùdarí, mo fé kín prò tí Asòfin fún Ekùn-idibò Etí-Osà Kejì (Onímó-èrọ G. O. R. Yishawu) sọ léyìn, ní agbègbè tèmi ní Erékùsù Èkó Kìnní tí opòlopo mộ sí Ilé Owó Èkó nítorí wí pé kò sí ohun tí ẹ fé, tí ẹ kò ní rí rà ní ibè.
Ní agbègbè Òróyìnyin, a ní ipèníjà lórí ojúnà àgbàrá tí ó ti n ba ilé àti okòwò àwọn èniyàn jé, kò sí àyè láti rìn kọjá. Ní òpin osè tó kojá, mo lọ síbệ láti lọ ra ojà, omi tí ó wà níbệ kọjá orúnkún mi àmọn ènìyàn ti n fi se okòwò láti ma fún ẹni tí ó fé kojá ní bàtà ojò (rain booth) mi o mộ ohun tí ó sẹlệ, àwọn kan sọ wí pé Ministry of Physical Planning and Urban Development àti àwọn
Ìlúbirin ní nkan tí wón fé se lórí rè pèlú Estate tí wón n kó síbệ, sùgbón a ti gbìyànjú láti se iwádìí àti ìgbésè tí a bá lè gbè.
Ní àfikún sí ohun tí Asòfin fún Ekùn-idibò Etí-Òsà Kejì (Onímo-erọ G. O. R. Yishawu) sọ, ní agbègbè ibi tí èmi n gbé láti wá sí Ilé Ìgbìmò
Link bridge, a lo ogbon iseju nitor dive sunkere
fàkere oko. Ní Parkview sí Banana Island wón ti n di omi ojú àgbàrá bò wá sínú Lagoon, súnkere fàkere ọkọ wà níbệ àwọn ènìyàn n wo wí pé kí ló lè fa súnkere fàkere. Láti Falomo Bridge títí ló sí Ozumba Mbadiwe, kò sí súnkere fàkere okọ sùgbón èyí tí ó súnmò ibi tí àwọn ènìyàn wa ní Lekki-Ikoyi Bridge a ní láti gba iwájú Parkview tí a bá fé jáde sí Afárá Third Mainland kí ènìyàn ma lo iséjú márundínlógójì ní agbègbè náà kí wón tó dé ibisé. Kíni ìdí tí ó fi selè béệ, àwọn wo ló n ta agbègbè yìí, tani wón gba lyộnda lówó rè láti se béệ.
Fún itesiwáju, èmi lérò wí pé ile wa ní ó jewa lógún ní Ìpínlè Èkó, ilè wá ni chun tí ó yẹ kí a dìmú. Kí wón tó gba ilè láti orí omi, reclamation ni à n pè é, wón máa n gba lyộnda, ta wá ni eni tí ó fún wọn ní iyònda láti ma lé omi séyìn, tí ó fi di ilè, tí a bá dúró s’órí afárá Lekki, a máa n ri bí wón se n lé omi nà séyìn kò dìgbà tí omi bá gbé àwọn aráàlú lọ kí a tó dide se ohun tí ó yẹ láti se.
Èmi fé gba lyònda lówó Ilé vìí wí pé kí wón fún wa ní àyè kí wón sì pe gbogbo àwọn tí ó wà nídìí ộrò náà ní kón mó-n-kóbó.